Sáàmù 34:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ebi máa ń pa àwọn ọmọ kìnnìún* tó lágbára,Àmọ́ ní ti àwọn tó ń wá Jèhófà, wọn kò ní ṣaláìní ohun rere.+ Sáàmù 37:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+
10 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ebi máa ń pa àwọn ọmọ kìnnìún* tó lágbára,Àmọ́ ní ti àwọn tó ń wá Jèhófà, wọn kò ní ṣaláìní ohun rere.+
25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+