Òwe 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọkàn ẹni tó ní òye ń gba ìmọ̀,+Etí ọlọ́gbọ́n sì ń wá ọ̀nà láti gbọ́ ìmọ̀.