Òwe 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Híhùwà àìnítìjú dà bí eré lójú òmùgọ̀,Àmọ́ ọgbọ́n wà fún ẹni tó ní òye.+ Òwe 30:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọ̀nà obìnrin alágbèrè nìyí: Ó jẹun, ó nu ẹnu rẹ̀;Ó sì sọ pé, “Mi ò ṣe nǹkan kan tó burú.”+