Òwe 16:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ọ̀nà kan wà tó dà bíi pé ó tọ́ lójú èèyàn,Àmọ́ nígbẹ̀yìn, á yọrí sí ikú.+