Òwe 12:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Òmùgọ̀ máa ń fi ìbínú rẹ̀ hàn lójú ẹsẹ̀,*+Àmọ́ aláròjinlẹ̀ máa ń gbójú fo* àbùkù tí wọ́n fi kàn án. Òwe 16:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni tí kì í tètè bínú+ sàn ju akíkanjú ọkùnrin,Ẹni tó sì ń kápá ìbínú rẹ̀* sàn ju ẹni tó ṣẹ́gun ìlú.+
16 Òmùgọ̀ máa ń fi ìbínú rẹ̀ hàn lójú ẹsẹ̀,*+Àmọ́ aláròjinlẹ̀ máa ń gbójú fo* àbùkù tí wọ́n fi kàn án.
32 Ẹni tí kì í tètè bínú+ sàn ju akíkanjú ọkùnrin,Ẹni tó sì ń kápá ìbínú rẹ̀* sàn ju ẹni tó ṣẹ́gun ìlú.+