Sáàmù 146:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà ń dáàbò bo àwọn àjèjì;Ó ń fún ọmọ aláìníbaba àti opó lókun,+Àmọ́, ó ń sọ èrò àwọn ẹni burúkú dòfo.*+
9 Jèhófà ń dáàbò bo àwọn àjèjì;Ó ń fún ọmọ aláìníbaba àti opó lókun,+Àmọ́, ó ń sọ èrò àwọn ẹni burúkú dòfo.*+