Sáàmù 139:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Tí mo bá lọ sọ́run, wàá wà níbẹ̀,Tí mo bá sì tẹ́ ibùsùn mi sínú Isà Òkú,* wò ó! wàá ti wà níbẹ̀.+