Òwe 15:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Oúnjẹ tí a fi nǹkan ọ̀gbìn sè níbi tí ìfẹ́ wà+Sàn ju akọ màlúù àbọ́sanra* níbi tí ìkórìíra wà.+