-
Jémíìsì 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ọlọ́gbọ́n àti olóye wo ló wà láàárín yín? Kó fi ìwà rere rẹ̀ hàn nínú bó ṣe ń fi ìwà tútù ṣe àwọn iṣẹ́ tó fi hàn pé ó gbọ́n.