Òwe 16:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ọkàn ọlọ́gbọ́n ń fún ẹnu rẹ̀ ní ìjìnlẹ̀ òye+Ó sì ń fi ìyíniléròpadà kún ọ̀rọ̀ rẹ̀.