ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Jèhófà wá na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fi kan ẹnu mi.+ Jèhófà sì sọ fún mi pé: “Mo ti fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ.+

  • Lúùkù 12:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Tí wọ́n bá mú yín wọlé síwájú ibi táwọn èèyàn pé jọ sí,* síwájú àwọn aṣojú ìjọba àti àwọn aláṣẹ, ẹ má ṣàníyàn nípa bí ẹ ṣe máa sọ̀rọ̀ tàbí ọ̀rọ̀ tí ẹ máa fi gbèjà ara yín tàbí ohun tí ẹ máa sọ,+ 12 torí ní wákàtí yẹn gan-an, ẹ̀mí mímọ́ máa kọ́ yín ní àwọn ohun tó yẹ kí ẹ sọ.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́