Sáàmù 119:111 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 111 Mo fi àwọn ìránnilétí rẹ ṣe ohun ìní mi tí á máa wà títí lọ,*Nítorí àwọn ni ayọ̀ ọkàn mi.+