4 Màá jẹ́ kí ọkàn Fáráò le,+ ó máa lépa wọn, màá sì ṣe ara mi lógo nípasẹ̀ Fáráò àti gbogbo ọmọ ogun rẹ̀.+ Ó dájú pé àwọn ará Íjíbítì yóò mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.”+ Ohun tí wọ́n sì ṣe nìyẹn.
21 Kí wá ni? Ṣé amọ̀kòkò ò láṣẹ lórí amọ̀+ láti fi lára ìṣùpọ̀ rẹ̀ mọ ohun èlò* kan fún ìlò tó lọ́lá, kí ó sì fi lára rẹ̀ mọ ohun èlò míì fún ìlò tí kò lọ́lá?