Òwe 20:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ọlọ́gbọ́n ọba máa ń yọ àwọn ẹni ibi sọ́tọ̀+Á sì wa àgbá kẹ̀kẹ́ ìpakà kọjá lórí wọn.+