Òwe 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọgbọ́n ni ohun tó ṣe pàtàkì* jù lọ,+ torí náà ní ọgbọ́n,Pẹ̀lú gbogbo ohun tí o sì ní, ní òye.+