Lúùkù 4:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Gbogbo wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í jẹ́rìí rẹ̀ ní rere, ẹnu ń yà wọ́n torí àwọn ọ̀rọ̀ tó tuni lára tó ń ti ẹnu rẹ̀ jáde,+ wọ́n sì ń sọ pé: “Ọmọ Jósẹ́fù nìyí, àbí òun kọ́?”+ Kólósè 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yín máa jẹ́ ọ̀rọ̀ onínúure, tí iyọ̀ dùn,+ kí ẹ lè mọ bó ṣe yẹ kí ẹ dá ẹnì kọ̀ọ̀kan lóhùn.+
22 Gbogbo wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í jẹ́rìí rẹ̀ ní rere, ẹnu ń yà wọ́n torí àwọn ọ̀rọ̀ tó tuni lára tó ń ti ẹnu rẹ̀ jáde,+ wọ́n sì ń sọ pé: “Ọmọ Jósẹ́fù nìyí, àbí òun kọ́?”+
6 Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yín máa jẹ́ ọ̀rọ̀ onínúure, tí iyọ̀ dùn,+ kí ẹ lè mọ bó ṣe yẹ kí ẹ dá ẹnì kọ̀ọ̀kan lóhùn.+