Oníwàásù 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Gbogbo iṣẹ́ àṣekára téèyàn ń ṣe, torí kó lè rí nǹkan fi sẹ́nu ni;+ síbẹ̀ kì í* yó.