Òwe 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìkà àti aláìwúlò ẹ̀dá ń rìn kiri tòun ti èké ọ̀rọ̀;+ Òwe 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Pẹ̀lú ọkàn burúkú,Ó ń gbèrò ibi ní gbogbo ìgbà,+ ó sì ń dá awuyewuye sílẹ̀.+
12 Ìkà àti aláìwúlò ẹ̀dá ń rìn kiri tòun ti èké ọ̀rọ̀;+ Òwe 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Pẹ̀lú ọkàn burúkú,Ó ń gbèrò ibi ní gbogbo ìgbà,+ ó sì ń dá awuyewuye sílẹ̀.+