1 Sámúẹ́lì 14:41, 42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún Jèhófà pé: “Ọlọ́run Ísírẹ́lì, fi Túmímù+ dáhùn!” Ni Túmímù bá mú Jónátánì àti Sọ́ọ̀lù, àwọn èèyàn náà sì bọ́. 42 Sọ́ọ̀lù wá sọ pé: “Ẹ ṣẹ́ kèké+ kí a lè mọ ẹni tó jẹ́ láàárín èmi àti Jónátánì ọmọ mi.” Túmímù sì mú Jónátánì. Ìṣe 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Wọ́n wá gbàdúrà, wọ́n sì sọ pé: “Jèhófà,* ìwọ ẹni tó mọ ọkàn gbogbo èèyàn,+ fi ẹni tí o yàn lára àwọn ọkùnrin méjì yìí hàn, Ìṣe 1:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nítorí náà, wọ́n ṣẹ́ kèké lé wọn,+ kèké sì mú Màtáyásì, a sì kà á mọ́* àwọn àpọ́sítélì mọ́kànlá (11).
41 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún Jèhófà pé: “Ọlọ́run Ísírẹ́lì, fi Túmímù+ dáhùn!” Ni Túmímù bá mú Jónátánì àti Sọ́ọ̀lù, àwọn èèyàn náà sì bọ́. 42 Sọ́ọ̀lù wá sọ pé: “Ẹ ṣẹ́ kèké+ kí a lè mọ ẹni tó jẹ́ láàárín èmi àti Jónátánì ọmọ mi.” Túmímù sì mú Jónátánì.
24 Wọ́n wá gbàdúrà, wọ́n sì sọ pé: “Jèhófà,* ìwọ ẹni tó mọ ọkàn gbogbo èèyàn,+ fi ẹni tí o yàn lára àwọn ọkùnrin méjì yìí hàn,
26 Nítorí náà, wọ́n ṣẹ́ kèké lé wọn,+ kèké sì mú Màtáyásì, a sì kà á mọ́* àwọn àpọ́sítélì mọ́kànlá (11).