Òwe 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìpinnu tó ní ìmísí* ló yẹ kó máa wà lẹ́nu ọba;+Kò gbọ́dọ̀ dá ẹjọ́ lọ́nà tí kò tọ́.+