Òwe 12:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àníyàn inú ọkàn máa ń mú kó rẹ̀wẹ̀sì,*+Àmọ́ ọ̀rọ̀ rere máa ń mú kó túra ká.+ Òwe 15:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Inú dídùn ló ń mórí yá,Àmọ́ ẹ̀dùn ọkàn máa ń fa ìrẹ̀wẹ̀sì.+