-
Oníwàásù 9:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó sàn kéèyàn tẹ̀ lé ọ̀rọ̀ jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ tí ọlọ́gbọ́n sọ ju kéèyàn máa fetí sí ariwo ẹni tó ń ṣàkóso láàárín àwọn òmùgọ̀.
-
-
Jémíìsì 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ọlọ́gbọ́n àti olóye wo ló wà láàárín yín? Kó fi ìwà rere rẹ̀ hàn nínú bó ṣe ń fi ìwà tútù ṣe àwọn iṣẹ́ tó fi hàn pé ó gbọ́n.
-