Òwe 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ọ̀rọ̀ bá ti pọ̀, àṣìṣe ò ní ṣàì wáyé,+Àmọ́ ẹni tó bá ń ṣọ́ ẹnu rẹ̀ á máa fi ọgbọ́n hùwà.+