Òwe 26:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọ̀rọ̀ abanijẹ́ dà bí òkèlè dídùn;*Tí a gbé mì sínú ikùn lọ́hùn-ún.+