-
Sáàmù 49:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ wọn,+
Tí wọ́n sì ń fi ọrọ̀ rẹpẹtẹ wọn fọ́nnu,+
7 Kò sí ìkankan nínú wọn tó lè ra arákùnrin kan pa dà
Tàbí tí ó lè fún Ọlọ́run ní ìràpadà nítorí rẹ̀,+
-
Jeremáyà 9:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
-
-
Lúùkù 12:19-21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 màá sì sọ fún ara* mi pé: “O ní* ọ̀pọ̀ nǹkan rere tí mo ti tò jọ fún ọ̀pọ̀ ọdún; fọkàn balẹ̀, máa jẹ, máa mu, máa gbádùn ara ẹ.”’ 20 Àmọ́ Ọlọ́run sọ fún un pé, ‘Aláìlóye, òru òní ni wọ́n máa béèrè ẹ̀mí* rẹ lọ́wọ́ rẹ. Ta ló máa wá ni àwọn ohun tí o ti tò jọ?’+ 21 Bẹ́ẹ̀ ló máa rí fún ẹni tó bá ń to ìṣúra jọ fún ara rẹ̀ àmọ́ tí kò ní ọrọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọ́run.”+
-
-
-