-
2 Sámúẹ́lì 16:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ọba wá béèrè pé: “Ọmọ* ọ̀gá rẹ ńkọ́?”+ Síbà dá ọba lóhùn pé: “Ó wà ní Jerúsálẹ́mù, nítorí ó sọ pé, ‘Lónìí, ilé Ísírẹ́lì máa dá ìjọba bàbá mi pa dà fún mi.’”+ 4 Ọba wá sọ fún Síbà pé: “Wò ó! Kí gbogbo ohun tó jẹ́ ti Méfíbóṣétì di tìrẹ.”+ Síbà sọ pé: “Mo tẹrí ba níwájú rẹ. Jẹ́ kí n rí ojú rere rẹ, olúwa mi ọba.”+
-