Òwe 15:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni tó bá ń kọ ìbáwí kórìíra ẹ̀mí* rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó bá ń gba ìbáwí ní òye.*+