Òwe 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kọ́ ọlọ́gbọ́n, yóò sì gbọ́n sí i. + Kọ́ olódodo, yóò sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i. Òwe 21:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà tí wọ́n bá fìyà jẹ afiniṣẹ̀sín, aláìmọ̀kan á kọ́gbọ́n,Nígbà tí ọlọ́gbọ́n bá sì rí ìjìnlẹ̀ òye, á ní ìmọ̀.*+
11 Nígbà tí wọ́n bá fìyà jẹ afiniṣẹ̀sín, aláìmọ̀kan á kọ́gbọ́n,Nígbà tí ọlọ́gbọ́n bá sì rí ìjìnlẹ̀ òye, á ní ìmọ̀.*+