-
Òwe 4:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Torí wọn ò lè sùn àfi tí wọ́n bá ṣe ohun tí kò dáa.
Wọn kì í rí oorun sùn àfi tí wọ́n bá mú kí ẹnì kan ṣubú.
17 Oúnjẹ ìwà burúkú ni wọ́n fi ń bọ́ ara wọn,
Wáìnì ìwà ipá ni wọ́n sì ń mu.
-