Òwe 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọgbọ́n wà ní ètè olóye,+Àmọ́ ọ̀pá wà fún ẹ̀yìn ẹni tí kò ní làákàyè.*+ Òwe 26:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Pàṣán wà fún ẹṣin, ìjánu wà fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,+Ọ̀pá sì wà fún ẹ̀yìn àwọn òmùgọ̀.+