1 Kọ́ríńtì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 àwọn olè, àwọn olójúkòkòrò,+ àwọn ọ̀mùtípara,+ àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn* àti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+ Gálátíà 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 ìlara, ìmutíyó,+ àwọn àríyá aláriwo àti irú àwọn nǹkan yìí.+ Mò ń kìlọ̀ fún yín ṣáájú nípa àwọn nǹkan yìí, lọ́nà kan náà tí mo gbà kìlọ̀ fún yín tẹ́lẹ̀, pé àwọn tó bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+ Éfésù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bákan náà, ẹ má ṣe máa mu wáìnì ní àmupara,+ torí ó ń yọrí sí ìwà pálapàla,* àmọ́ ẹ máa kún fún ẹ̀mí.
10 àwọn olè, àwọn olójúkòkòrò,+ àwọn ọ̀mùtípara,+ àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn* àti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+
21 ìlara, ìmutíyó,+ àwọn àríyá aláriwo àti irú àwọn nǹkan yìí.+ Mò ń kìlọ̀ fún yín ṣáájú nípa àwọn nǹkan yìí, lọ́nà kan náà tí mo gbà kìlọ̀ fún yín tẹ́lẹ̀, pé àwọn tó bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+
18 Bákan náà, ẹ má ṣe máa mu wáìnì ní àmupara,+ torí ó ń yọrí sí ìwà pálapàla,* àmọ́ ẹ máa kún fún ẹ̀mí.