Òwe 14:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹni tí kì í tètè bínú ní ìjìnlẹ̀ òye,+Àmọ́ ẹni tí kò ní sùúrù ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.+ 2 Tímótì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Bákan náà, má ṣe dá sí àwọn ìjiyàn tí kò bọ́gbọ́n mu àti ti àìmọ̀kan,+ o mọ̀ pé wọ́n máa ń fa ìjà.
23 Bákan náà, má ṣe dá sí àwọn ìjiyàn tí kò bọ́gbọ́n mu àti ti àìmọ̀kan,+ o mọ̀ pé wọ́n máa ń fa ìjà.