Òwe 18:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọ̀rọ̀ ẹnu òmùgọ̀ máa ń dá ìjà sílẹ̀,+Ẹnu rẹ̀ sì máa ń mú kí wọ́n lù ú.+ Oníwàásù 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Má ṣe máa yára* bínú,+ torí pé àyà àwọn òmùgọ̀ ni ìbínú ń gbé.*+