1 Àwọn Ọba 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó tún kọ́ Gbọ̀ngàn* Ìtẹ́,+ níbi tí yóò ti máa ṣe ìdájọ́, ìyẹn Gbọ̀ngàn Ìdájọ́,+ wọ́n sì fi igi kédárì ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́ láti ìsàlẹ̀ dé ibi igi ìrólé lókè.
7 Ó tún kọ́ Gbọ̀ngàn* Ìtẹ́,+ níbi tí yóò ti máa ṣe ìdájọ́, ìyẹn Gbọ̀ngàn Ìdájọ́,+ wọ́n sì fi igi kédárì ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́ láti ìsàlẹ̀ dé ibi igi ìrólé lókè.