Òwe 11:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹni tó bá ṣe onídùúró* fún àjèjì yóò rí láburú,+Àmọ́ ẹni tó bá yẹra fún* bíbọ ọwọ́ nínú ẹ̀jẹ́ yóò rí ààbò.
15 Ẹni tó bá ṣe onídùúró* fún àjèjì yóò rí láburú,+Àmọ́ ẹni tó bá yẹra fún* bíbọ ọwọ́ nínú ẹ̀jẹ́ yóò rí ààbò.