Òwe 27:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Gba ẹ̀wù ẹni tó bá ṣe onídùúró fún àjèjì;Tó bá sì jẹ́ pé obìnrin àjèjì* ló ṣe é fún, gba ohun tó fi ṣe ìdúró lọ́wọ́ rẹ̀.+
13 Gba ẹ̀wù ẹni tó bá ṣe onídùúró fún àjèjì;Tó bá sì jẹ́ pé obìnrin àjèjì* ló ṣe é fún, gba ohun tó fi ṣe ìdúró lọ́wọ́ rẹ̀.+