Òwe 6:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àwọn èèyàn kì í pẹ̀gàn olèTó bá jẹ́ pé ebi tó ń pa á ló mú kó jalè kó lè tẹ́ ọkàn* rẹ̀ lọ́rùn. 31 Síbẹ̀, tí wọ́n bá rí i, á san án pa dà ní ìlọ́po méje;Gbogbo ohun tó níye lórí nínú ilé rẹ̀ ló máa kó sílẹ̀.+
30 Àwọn èèyàn kì í pẹ̀gàn olèTó bá jẹ́ pé ebi tó ń pa á ló mú kó jalè kó lè tẹ́ ọkàn* rẹ̀ lọ́rùn. 31 Síbẹ̀, tí wọ́n bá rí i, á san án pa dà ní ìlọ́po méje;Gbogbo ohun tó níye lórí nínú ilé rẹ̀ ló máa kó sílẹ̀.+