Òwe 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Láìsí ìfinúkonú,* èrò á dasán,Àmọ́ nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ agbani-nímọ̀ràn,* àṣeyọrí á wà.+