Léfítíkù 19:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 “‘Kí o dìde níwájú orí ewú,+ kí o máa bọlá fún àgbàlagbà,+ kí o sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run+ rẹ. Èmi ni Jèhófà. Òwe 16:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ewú orí jẹ́ adé ẹwà*+Nígbà tí a bá rí i ní ọ̀nà òdodo.+
32 “‘Kí o dìde níwájú orí ewú,+ kí o máa bọlá fún àgbàlagbà,+ kí o sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run+ rẹ. Èmi ni Jèhófà.