Sáàmù 36:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ẹ̀ṣẹ̀ jinlẹ̀ lọ́kàn ẹni burúkú;Kò sí ìbẹ̀rù Ọlọ́run lójú rẹ̀.+ 2 Ó ń pọ́n ara rẹ̀ lé ju bó ṣe yẹ lọDébi pé kò rí àṣìṣe ara rẹ̀, kí ó sì kórìíra rẹ̀.+ Òwe 16:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gbogbo ọ̀nà èèyàn máa ń tọ́* lójú ara rẹ̀,+Àmọ́ Jèhófà máa ń ṣàyẹ̀wò èrò ọkàn.*+
36 Ẹ̀ṣẹ̀ jinlẹ̀ lọ́kàn ẹni burúkú;Kò sí ìbẹ̀rù Ọlọ́run lójú rẹ̀.+ 2 Ó ń pọ́n ara rẹ̀ lé ju bó ṣe yẹ lọDébi pé kò rí àṣìṣe ara rẹ̀, kí ó sì kórìíra rẹ̀.+