Òwe 15:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Òmùgọ̀ kì í ka ẹ̀kọ́ bàbá rẹ̀ sí,+Àmọ́ aláròjinlẹ̀ máa ń gba ìbáwí.*+