Nọ́ńbà 14:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Síbẹ̀, wọ́n ṣorí kunkun,* wọ́n sì lọ sí orí òkè+ náà, àmọ́ àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti Mósè kò kúrò ní àárín ibùdó.+ Ẹ́sítà 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn náà, ọba sọ pé: “Ta ló wà ní àgbàlá?” Ní àkókò yìí, Hámánì ti dé sí àgbàlá ìta+ ilé* ọba láti sọ fún ọba bí wọ́n ṣe máa gbé Módékáì kọ́ sórí òpó igi tó ti ṣe fún un.+
44 Síbẹ̀, wọ́n ṣorí kunkun,* wọ́n sì lọ sí orí òkè+ náà, àmọ́ àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti Mósè kò kúrò ní àárín ibùdó.+
4 Lẹ́yìn náà, ọba sọ pé: “Ta ló wà ní àgbàlá?” Ní àkókò yìí, Hámánì ti dé sí àgbàlá ìta+ ilé* ọba láti sọ fún ọba bí wọ́n ṣe máa gbé Módékáì kọ́ sórí òpó igi tó ti ṣe fún un.+