Òwe 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Òdodo aláìlẹ́bi ń mú kí ipa ọ̀nà rẹ̀ tọ́,Àmọ́ ẹni burúkú á ṣubú nítorí ìwà burúkú rẹ̀.+