-
Mátíù 18:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Àmọ́ torí pé kò ní ohun tó máa fi san án pa dà, ọ̀gá rẹ̀ pàṣẹ pé kí wọ́n ta òun, ìyàwó rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo ohun tó ní, kí wọ́n sì fi san gbèsè náà.+
-