Sáàmù 45:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ lo rẹwà jù lọ nínú àwọn ọmọ èèyàn. Ọ̀rọ̀ rere ń jáde lẹ́nu rẹ.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run fi bù kún ọ títí láé.+ Òwe 16:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ òdodo jẹ́ ìdùnnú àwọn ọba. Wọ́n fẹ́ràn ẹni tó bá ń sọ òótọ́.+ Mátíù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Aláyọ̀ ni àwọn tí ọkàn wọn mọ́,+ torí wọ́n máa rí Ọlọ́run.
2 Ìwọ lo rẹwà jù lọ nínú àwọn ọmọ èèyàn. Ọ̀rọ̀ rere ń jáde lẹ́nu rẹ.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run fi bù kún ọ títí láé.+