Sáàmù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”* Òwe 14:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹni tó ń lu aláìní ní jìbìtì ń gan Ẹni tó dá a,+Àmọ́ ẹni tó ń ṣàánú tálákà ń yìn Ín lógo.+
5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”*