Òwe 15:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọkàn tó ní òye máa ń wá ìmọ̀,+Àmọ́ ìwà ẹ̀gọ̀ ni àwọn òmùgọ̀ fi ń ṣe oúnjẹ jẹ.*+