Sáàmù 107:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ẹni tó bá gbọ́n yóò kíyè sí àwọn nǹkan yìí,+Yóò sì fara balẹ̀ kíyè sí àwọn ohun tí Jèhófà ṣe nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.+
43 Ẹni tó bá gbọ́n yóò kíyè sí àwọn nǹkan yìí,+Yóò sì fara balẹ̀ kíyè sí àwọn ohun tí Jèhófà ṣe nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.+