Sáàmù 62:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bákan náà, ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ jẹ́ tìrẹ, Jèhófà,+Nítorí o máa ń san kálukú lẹ́san iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.+ Mátíù 16:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí Ọmọ èèyàn máa wá nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀, ó máa wá san èrè fún kálukú gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ̀.+ Róòmù 2:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́ nítorí agídí rẹ àti ọkàn rẹ tí kò ronú pìwà dà, ò ń kó ìrunú jọ sórí ara rẹ, ìrunú yìí máa hàn ní ọjọ́ ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run.+ 6 Yóò san kálukú lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀:+
27 Torí Ọmọ èèyàn máa wá nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀, ó máa wá san èrè fún kálukú gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ̀.+
5 Àmọ́ nítorí agídí rẹ àti ọkàn rẹ tí kò ronú pìwà dà, ò ń kó ìrunú jọ sórí ara rẹ, ìrunú yìí máa hàn ní ọjọ́ ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run.+ 6 Yóò san kálukú lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀:+