Fílípì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ohun tí ẹ kọ́, tí ẹ tẹ́wọ́ gbà, tí ẹ gbọ́, tí ẹ sì rí lọ́dọ̀ mi, ẹ máa fi wọ́n sílò,+ Ọlọ́run àlàáfíà yóò sì wà pẹ̀lú yín.
9 Àwọn ohun tí ẹ kọ́, tí ẹ tẹ́wọ́ gbà, tí ẹ gbọ́, tí ẹ sì rí lọ́dọ̀ mi, ẹ máa fi wọ́n sílò,+ Ọlọ́run àlàáfíà yóò sì wà pẹ̀lú yín.